TOJU IWA RE ORE MI (Written by the late J.F. ODUNJO in his popular book series ‘ALAWIYE’) Tọ́jú TỌ́JÚ ÌWÀ RẸ Ọ̀RẸ́ MI (Written by the late J.F. ỌDÚN JỌ in his popular book series ‘ALÁWÍYẸ́’) Tọ́jú ìwà rẹ, ọ̀rẹ́ mi; Ọlá a máa sí lọ ní lé ẹni, Ẹwà a sì ma sí lára ènìyàn, Olówó ńd’olọ̀sì bó dọ̀la. Òkun l'ọlá; òkun n’ìgbì ọrò, Gbogbo wọn ló ńsí lo nílé ẹni; Ṣùgbọ́n ìwà ni ḿ’bá ni dé sàréè. Owó kò jẹ́ ǹkan fún ni, Ìwà l'ewà ọmọ ènìyàn. Bí o lówó bí o kò níwà ńkọ́? Taní jẹ́ f'inú tán ẹ bá ọ s'ohun rere? Tàbí kí o jẹ́ obìnrin rọ̀gbọ̀dọ̀; Tí o bá jìnà síwà tí ẹ̀dá ń fé , Taní jẹ́ fẹ́ o sílé bí aya? Tàbí kí o jẹ́ oníjìbìtì ènìà; Bí o tilè mo ìwé àmọ̀ dájú , Taní jẹ́ gbé'sé ajé fún ọ se? Tọ́jú Ìwà re, ọ̀rẹ́ mi, Ìwà kò sí , ẹ̀kọ́ dè gbé; Gbogbo ayé ni ń fẹ́ ni tó jẹ́ rere. (ENGLISH TRANSLATION) Enhance your character, my friend; Prosperity may depart from one’s home, Beauty may retreat from the body, And today’s rich could become poor tomo...
Temperament and character part 2 Phlegmatic The Phlegmatic temperament has three combinations: Phlegmatic-Choleric, Phlegmatic-Sanguine, and Phlegmatic-Melancholy. The traits of the primary temperament, Phlegmatic, may be altered or modified in some significant way determined by the influence of the secondary temperament. Remember, there are at least three levels of intensity of a temperament: classic, moderate, and mild. Some Phlegmatics will be very strong, others somewhat strong, and still others more mild. Phlegmatics are naturally service-oriented. They are passive in both favorable and unfavorable environments. They influence their environment by cooperating with others to carry out the task. They tend to not be highly ambitious and they tend to lack a sense of urgency (both due to their passive nature). Phlegmatics are introverted, calm, unemotional, easygoing, indecisive, patient, and agreeable. They are both slow and indirect when responding to others. Phlegmatic...
Comments
Post a Comment